Lyrics

LYRICS: Agbara Orun – Roseline Effiong

Agbara Orun Lyrics – Roseline Effiong |

Chorus:
Sokale agbara orun
Emi omo Re mo nilo agbara Re
Agbara ti nsegun ese
Agbara ti ngbe’ku mi
Sokale Jesu sinu aye mi

Solo:
1) Gbogbo agbara l’aye at’ orun
Jesu o mbe lowo Re
Agbara tin ji oku dide
To ns’ise iyanu
Sokale Jesu sinu aye mi

2) Agbara nla lat’oke orun
Agbara t’aye ko le doju ko
Agbara to laju afoju
To n s’agan d’olomo
Sokale Jesu sinu aye mi

3) Agbara ti ki iti, gbara ti ki isa
Agbara to lana so ri okun
Agbara to nso ni d’otun
To n fun ni l’omi nira
Sokale Jesu sinu aye mi

Bridge:
Agbara nla
Sokale Jesu sinu aye mi
Agbara isoji
Sokale Jesu sinu aye mi
Agbara ajinde
Sokale Jesu sinu aye mi
Agbara ti n b’ori
Sokale Jesu sinu aye mi
L’atoke orun
Sokale Jesu sinu aye mi
Sokale Baba
Sokale Jesu sinu aye mi

Related Articles

Back to top button

You cannot copy content of this page

Adblock Detected

Please consider supporting us by disabling your ad blocker